Education resource centre


YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ



Yüklə 1,25 Mb.
səhifə7/16
tarix28.07.2018
ölçüsü1,25 Mb.
#60921
1   2   3   4   5   6   7   8   9   10   ...   16



YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

ÀŚÀ: Ìśêdálê àti Ìtànkálê Ômô Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Ìśêdálê Yorùbá láti õdõ Odùduwà

  2. Àwôn ìlú tí ó jë ti Yorùbá

d. Orúkô àwôn ômô Odùduwà

OLÙKÖ

a. Śe àlàyé àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé ní àgbáyé

b. Fi ìtàn àti àwòrán máàpù śe àlàyé bí Yorùbá śe śê àti bí wôn śe dé ibi tí wôn wà báyìí.b

AKËKÕÖ

a. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé.

b. Tún ìtàn náà sô

d. Kô kókó ìdánilëkõö sílê



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Máàpù Áfíríkà àti ilê Yorùbá

b. Máàpù Nàìjíríà àti ti àgbáyé tí ó śàfihàn ìtànkálê Yorùbá.


2.

FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Álífábëêtì Yorùbá

b. Kíka álífábëêtì láti A – Y

d. Àlàyé lórí lëtà ńlá àti lëtà kékeré

e. Ìsõrí álífábëêtì èdè Yorùbá (B.a. köńsónáýtì àti fáwëlì àìránmúpè àti fáwëlì àránmúpè)

ç. Ìyàtõ láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.



OLÙKÖ

a. Ka álífábëêtì fún àwôn akëkõö.

b. Śe àlàyé lórí lëtà ńlá àti kékeré

d. Pín álífábëêtì èdè Yorùbá sí ìsõrí köńsónáýtì àti fáwëlì

e. Fi ìyàtõ hàn láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Kádíböõdù tí a kô álífábëêtì Yorùbá sí.

b. Káàdì pélébé pélébé tí a kô lëtà kõõkan sí.


3.

ÀŚÀ: Ìkíni

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò (B.a. àárõ, õsán, alë, òru, ìyálêta, ààjìn abbl)

b. Ìkíni fún onírúurú ayçyç (Bí ìsômôlórúkô, ìgbéyàwó, ôlöjö ìbí, oyè jíjç, ìkíni fún aláboyún abbl).

d. Ìkíni fún onírúurú iśë. Bí àpççrç: àgbê, ôdç, akõpç, onídìrí, aláró, awakõ, alágbêdç, babaláwo abbl.



OLÙKÖ

a. Śe àlàyé ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò

b. Śe àlàyé ìkíni fún onírúurú ayçyç

d. Śe àlàyé ìkíni fún onírúurú iśë



AKËKÕÖ

a. Dárúkô àkókò àti ìgbà tó wà nínú ôjö.

b. Kí ènìyàn bí ó ti yç ní àkókò kõõkan.

d. Kí ènìyàn bí ó ti yç fún onírúurú ayçyç.

e. Kí ènìyàn fún onírúurú iśë

ç. Hùwà bí ó śe yç ní àsìkò ìkíni (B.a. ìkúnlê, ìdõbálê)



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Pátákó tí a kô onírúurú ìkíni sí.

b. Àwòrán àwôn ômô tí wôn ń kí obi wôn.


4.

ÈDÈ: Àkàyé

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Kíka àwôn ìtàn kéèkèèké ôlörõ geere àti ewì.

b. Títúmõ àwôn õrõ tí ó ta kókó inú àyôkà.

d. Ìbéèrè àti ìdáhùn lórí àyôkà.



OLÙKÖ

a. Jë kí akëkõö ka àyôkà náà lëêmejì ó kéré tán.

b. Tö akëkõö sönà láti lè fa kókó õrõ inú àyôkà yô.

d. Béèrè ìbéèrè lórí àyôkà náà



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí olùkö

b. Ka àyôkà náà ni àkàsínú – àkàsíta

d. Dáhùn ìbéèrè àyôkà

e. Jíròrò lórí ìtumõ õrõ pàtàkì pàtàkì àti àkànlò-èdè inú àyôkà náà, kí o sì kô ö sínú ìwé

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Pátákó ìkõwé

b. ìwé atúmõ èdè


5.

ÀŚÀ: Àśà Ìgbéyàwó Nílê Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìtumõ àti oríśi ìgbéyàwó

b. Àwôn ìgbésê ìgbéyàwó bí i ìfojúsóde, alárinà, ìtôrô, ìjöhçn tàbí ìśíhùn, ìdána abbl

d. Àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò wôn.



OLÙKÖ

a. śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìtumõ ìgbéyàwó

b. Jë kí àwôn akëkõö töka sí ìgbésê ìgbéyàwó

d. Kí olùkö jë kí àwôn akëkõö dárúkô àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò rê



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí olùkö.

b. Jíròrò nípa ìrírí rê

d. Da õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó kô sínú ìwé wôn.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- Àwòrán ìgbéyàwó

- Fídíò

- Téèpù


- Tçlifísàn

6.

ÈDÈ: Àkôtö

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àtúnyêwò álífábëêtì èdè Yorùbá

b. ìtumõ àkôtö

d. sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní

e. ìyàtõ láàrin sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní.

i. Fáwëlì: aiye – ayé

yio – yóò

enia – ènìyàn, abbl

ii. Köńsónáýtì: Oshogbo - Òśogbo, abbl

iii. Àmì ohùn: õgun - òógùn

alãnu – aláàánú

iv. Yíyán õrõ nídìí: ẹ - ç , ṣ - ś, ọ - ô

v. Pípín õrõ: wipe – wí pé

nigbati – nígbà tí



OLÙKÖ

a. Śe àlàyé ohun tí àkôtö jë

b. kô àkôtö àtijö àti òde òní sára pátákó

d. Śe àlàyé kíkún lórí ìyàtõ láàrin méjèèjì



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. kô àpççrç tí olùkö kô sí ojú pátákó

d. Béèrè ohun tí kò bá yé ô löwö olùkö.



7.

LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìtumõ oríkì lítírèśõ

b. Êka lítírèśõ Yorùbá

i. Lítírèśõ Àpilêkô

ii. Lítírèśõ Alohùn

d. Ìsõrí Lítírèśõ àpilêkô

i. Àpilêkô ôlörõ geere

ii. àpilêkô ewì

iii. àpilêkô eré-onítàn

e. Ìsõrí lítírèśõ alohùn

i. ôlörõ geere

ii. ewì alohùn

iii. eré-oníśe



OLÙKÖ

a. Śe àlàyé ohun tí lítírèśõ jë

b. Sô çka lítírèśõ

d. pín êka kõõkan sí ìsõrí pêlú àpççrç tí ó yç

e. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin àpilêkô àti alohùn.

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. kô àwôn êka àti ìsõrí tí olùkö sô sílê pêlú àpççrç

d. kô àpççrç mìíràn sí láti ilé



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- Téèpù


- Tçlifísàn

- Rédíò


- kásëëtì àti téèpù tí a gba ohùn sí

- Fíìmù ìśeré lítírèśõ alohùn

- ìwé tí a da lítírèśõ alohùn kô sí


8.

LÍTÍRÈŚÕ: Òýkà Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Òýkà Õödúnrún dé irínwó (300 – 400)



OLÙKÖ

a. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti Õödúnrún dé irínwó

b. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún

AKËKÕÖ

a. ka òýkà láti Õödúnrún dé irínwó

b. dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan

d. kô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- Kádíböõdù tí a kô òýkà láti Õödúnrún dé irínwó

- Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí


9.

ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. õrõ-orúkô

b. õrõ aröpò- orúkô/ aröpò afarajorúkô

d. õrõ-ìśe

e. õrõ-àpèjúwe

ç. õrõ-àpönlé

f. õrõ-atökùn

g. õrõ-àsopõ



OLÙKÖ

a. śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë õkõõkan nínú gbólóhùn.

b. śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö

d. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí kõõkan

b. kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé

d. śe àwôn àpççrç tirê lábë ìdarí olùkö.



OHUN ÈLÒ ÌKÖNI

a. Kádíböõdù

b. Káàdì pélébé pélébé.


10.

ÀŚÀ: Òwò Śíśe àti Ìpolówó Ôjà

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. ìdí tí a fi ń polówó ôjà

b. bí a śe ń polówó kõõkan. Bí àpççrç; Ç fçran jêkô

d. ôgbön ìpolówó ôjà láyé àtijö àti lóde òní. Bí àpççrç: ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.



OLÙKÖ

a. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö.

b. fún àwôn akëkõö láýfààní láti śe ìpolówó ôjà nínú kíláásì.

d. kí akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ.



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê

b. kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì

d. śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. àtç


b. fídíò

d. êrô agbõrõsílê

e. Téèpù

ç. ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn



11.

ÈDÈ: Ìśêdá Õrõ-Orúkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. kí ni õrõ-orúkô?

b. oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç.

d. Àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.



OLÙKÖ

a. Śe àlàyé ohun tí õrõ-orúkô jë

b. śe àlàyé oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç: çja, ejò, ìyá, ôwö, êrín, adé, abö, jíjç, alaalë abbl

d. śe àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. śe àpççrç õrõ-orúkô tí a kò śêdá mìíràn

d. śe àpççrç àwôn oríśiríśi õrõ-orúkô tí a śêdá mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö ti śe.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. kádíböõdù tí a kô oríśiríśi àpççrç sí.



12.

ÈDÈ: Àròkô kíkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àlàyé lórí àròkô kíkô

b. Oríśiríśi àròkô

d. Ìgbésê



OLÙKÖ

a. Tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí aroko

b. Töka sí onírúurú àròkô pêlú àpççrç

d. śe àlàyé ìgbésê fún kíkô àròkô



AKËKÕÖ

a. Jíròró lórí àròkô

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. sô àpççrç àròkô mìíràn yàtõ sí ti olùkö

e. kópa nínú śíśe àlàyé ìgbésê àròkô

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- pátákó tí a kô oríśi àròkô sí

- pátákó tí a kô ìgbésê àròkô sí.


13.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ




14.

ÌDÁNWÒ




YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

FÓNËTÍÌKÌ: Àwôn êyà ara fún ìró èdè pípè

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró

b. Oríśi àfipè:

i. Àwôn êyà ara tí a lè fi ojú rí

ii. Àwôn êyà ara tí a kò lè fojú rí

iii. Àfipè àsúnsí

iv. Àfipè àkànmölê


OLÙKÖ

a. Śe àlàyé àwôn êyà ara tí a ń lò fún àwôn ìró èdè pípè

b. Tö akëkõö sönà láti dárúkô êyà ara àfipè àti ìwúlò wôn.

d. Dárúkô oríśi àfipè pêlú àlàyé kíkún



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Dárúkô àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró têlé olùkö

d. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé wôn



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- Àwòrán àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró tí a yà sí ara kádíböõdù

- Káàdì pélébé pélébé tí a kô êyà ara ifõ kõõkan sí.


2.

ÀŚÀ: Oyún níní àti ìtöjú Aláboyún

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìgbàgbö Yorùbá nípa àgàn, ômô bíbí àti àbíkú

b. Àwôn tí oyún níní wà fún (tôkôtaya)

d. Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjô

e. oríśiríśi jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó lè fëra wôn.

ç. Aájò láti lè tètè lóyún – àýfààní kíkóra-çni-níjàánu nípa ìbálòpõ

f. Bí a śe ń töjú aboyún látijô àti lóde òní:

Àtijö;


  • Oyún dídè, èèwõ aláboyún, àsèjç, àgbo abbl

Òde òní

  • Oúnjç aśaralóore, lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba) abbl

OLÙKÖ

a. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìgbàgbö àwôn Yorùbá nípa oyún níní, ìtöjú oyún àti àsìkò tó tö láti lóyún

b. Śe àlàyé onírúurú jënótáìpù êjê tí ó wà àti èyí tí ó bára mu

d. Kô àwôn oúnjç aśaralóore tí aboyún lè jç sára pátákó ìkõwé

e. Śe àlàyé bí a śe ń töjú aláboyún látijö àti lóde òní

ç. Śe àlàyé nípa pàtàkì ìkóra-çni-ní-ìjánu sáájú ìgbéyàwó fún çni tí ó bá tètè fë ômô bí



AKËKÕÖ

a. Sõrõ nípa àwôn tóyún wà fún

b. Sô ohun tí o mõ nípa oyún

d. Sô jënótáìpù tìrç

e. Dárúkô díê lára àwôn oúnjç aśaralóore

ç. Dárúkô díê lára àwôn õnà tí a fi ń töjú aláboyún látijô àti lóde òní

f. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Àwòrán aboyún

b. Àwòrán díê lára ohun-èlò tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà ti ìbílê: kòkò àgbo, ìsaasùn àśèjç, ìgbàdí abbl

d. Àwòrán díê lára ohun tí a fi töjú aláboyún ní òde òní

e. Àtç tí ó ń fi oúnjç aśaralóore hàn.


3.

ÈDÈ: Ìdámõ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Dídá nýkan mõ ní ilé-êkö àti inú ilé.

b. Dárúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë sí ara wôn

d. Dárúkô díê nínú àwôn êyà ara wa; ojú, imú, ôwö, çsê abbl



OLÙKÖ

a. Dárúkô nýkan díê nínú ilé àti ilé-êkö

b. Sô orúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë sí ara wôn.

d. Töka sí orúkô àwôn çranko díê

e. Sô díê nínú àwôn êyà ara wa.

AKËKÕÖ

a. Dárúkô àwôn nýkan díê nílé-êkö àti ní ilé yàtõ sí ti olùkö.

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Sô díê nínú orúkô àwôn çranko

e. Töka sí êyà ara rç

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- Àwòrán àwôn nýkan nílé-ìwé àti inú ilé

- Àwòrán çranko

- Àwòrán êyà ara



4.

ÀŚÀ: Àkókò, ìgbà àti ojú ôjö

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ôjö tó wà nínú õsê

b. orúkô àwôn ośù nínú ôdún

d. Sísô iye agogo tó lù



OLÙKÖ

a. Dárúkô ôjö tó wà nínú õsê àti àśà Yorùbá tó rõmö õkõõkan wôn.

b. Sô orúkô àwôn ośù tó wà nínú ôdún.

d. Sô iye agogo tó lù ní èdè Yorùbá pêlú õpõlôpõ àpççrç



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Dárúkô ôjö tó wà nínú õsê

d. Sô orúkô àwôn ośù tó wà nínú ôdún

e. Sô iye agogo tó lù yàtõ sí ti olùkö.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- kádíböõdù tí a kô orúkô ôjö àti ośù nínú ôdún sí.

- Ago ara ògiri

- Àwòrán ago tó ń fi onírúurú àkókò hàn.



5.

ÈDÈ: Lëtà Kíkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríśi lëtà: lëtà gbêfê àti àìgbagbêfê

b. Ìyàtõ àárin wôn

d. ìlànà kíkô lëtà gbêfê

- àdírësì, déètì, kíkô õrõ inú lëtà kí a sì pín-in sí ègé afõ bí ó ti yç.

- àsôkágbá/ àgbálôgbábõ/ ìgúnlê

e. ìlapa kíkô lëtà àìgbagbêfê

- Àdírësì

- Déètì

- Àkôlé


- Õrõ inú lëtà tí a pín sí ègé afõ bí ó ti yç.

OLÙKÖ

a. Sô oríśi lëtà kíkô méjì tí ó wà fún akëkõö

b. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin méjèèjì

d. Lo ìlapa kíkô lëtà gbêfê àti àìgbêfê láti töka sí ìyàtõ wôn

e. Tö akëkõö láti kô oríśi lëtà méjì

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Kô ìlapa kíkô oríśi lëtà – gbêfê àti àìgbêfê bí olùkö śe àlàyé rê/ kô ö sára pátákó.

d. Têlé ìtösönà olùkö láti kô oríśi lëtà méjì



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

- Pátákó çlëmõö àti kádíböõdù tí a kô ìlànà méjèèjì sí



6.

LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà (Àśàyàn Ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere)

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ibùdó àti ahunpõ ìtàn

b. Àśà tó súyô

d. Àwôn kókó õrõ tó súyô

e. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá

ç. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè



OLÙKÖ

a. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí êdá ìtàn dálé

b. śe àlàyé ìbáyému àkóónú ìtàn náà (ìśêlê, kókó-õrõ)

d. Jíròrò lórí ìwà êdá ìtàn pêlú akëkõö

e. Jíròrò lórí ìlò èdè àti àśà tó súyô

AKËKÕÖ

a. Ka ìtàn náà kí o sì jíròrò lórí ìśêlê inú rê (àhunpõ ìtàn)

b. sõrõ lórí êdá ìtàn tí wön fëràn àti èyí tí wôn kò fëràn

d. śe àfàyô ìlò ônà èdè àti ìsôwölo ônà èdè

e. śe àfàyô àśà tó súyô

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. ìwé asayan

b. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tí ó fara pë ti inú ìtàn tó wáyé wà.


7

ÀŚÀ: Eré Ìdárayá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. ìtumõ eré ìdárayá

b. Oríśiríśi eré ìdárayá

i. Eré òśùpá bí i – bojúbojú, ta ló wà nínú ôgbà náà abbl

ii. Eré ojoojúmö – àlö pípa, òkòtó, àrìn títa, ayò títa


OLÙKÖ

a. Śe àlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá.

b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá náà.

d. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákó



AKËKÕÖ

a. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö.

b. Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ

d.Tëtí sí àlàyé olùkö.

e. Kópa nínú eré ìdárayá tí olùkö darí.

ç. kô eré ìdárayá tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Ôpön ayò

  • Ômô ayò

  • Òkòtó

  • Àrìn abbl

8.

ÈDÈ: Òýkà

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. kíka irínwó – êëdëgbêta ní èdè Yorùbá: bí àpççrç;

okòólénírínwó – 420

ojìlénírinwó – 440

õtàlénírínwó – 460

õrìnlénírínwó – 480 abbl

b. Kíka òýkà àárin wôn. Bí àpççrç:

oókanlénírínwó – 401

èjìlénírínwó – 402 abbl


OLÙKÖ

a. Kô òýkà sí ara pátákó

b. Śe àlàyé ìlànà okòó, òjì, õtà, õrìn

- Àwôn òýkà àárin wôn

d. Śe ìdánwò akëkõö lórí àwôn òýkà náà

AKËKÕÖ

a. Da àwôn òýkà tí olùkö kô sí ara pátákó kô ö sí inú ìwé rç

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Śe ìdánwò tí olùkö pàśç ní kíláásì



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  1. Kádíböõdù

  2. Káàdì pélébé pélébé

9.

LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Ewì

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Ewì kíkà

  2. Kókó õrõ ajçmö-õrõ-tó-ń-lô láwùjô/ lágbàáyé.

  • Ìśêföfábo

  • ipò obìnrin

  • ètò ôrõ-ajé

  • ìkôlura êsìn/ àśà

  • ìkóra-çni-ní-ìjánu nínú ìgbésí ayé õdö

d. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè

OLÙKÖ

a. ka ewì sí akëkõö létí

b. śe àlàyé lórí ewì tí a kà

d. fa kókó õrõ jáde

e. śe àlàyé ônà èdè àti ìsôwölo-èdè tó jçyô

AKËKÕÖ

a. Ka ewì náà sinu

b. ka ewì náà síta

d. fi pëńsù fàlà sí ibi tí wön ti kíyèsí kókó õrõ àti êkö tí wön rí kö

e. Töka sí ônà èdè àti ìsôwölo-èdè

ç. Tëtí sí àlàyé olùkö



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Ìwé tí a yàn

b. Àwòrán ohun tí ewì dálé

d. Ìwé ìròyìn tí ó sô nípa àwôn kókó õrõ



10.

ÈDÈ: Ìró Èdè Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì

  2. Àpèjúwe ìró fáwëlì

d. Àtç fáwëlì àti köńsónáýtì

OLÙKÖ

a. Töka sí õnà tí á ń gbà śàpèjúwe köńsónáýtì àti fáwëlì

b. Śe àpèjúwe konsonati àti fáwëlì

d. Ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì

e. Dán àwôn akëkõö wò lórí àpèjúwe köńsónáýtì àti fáwëlì

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Śàjùwé ìró köńsónáýtì àti fáwëlì

d. Kô àpèjúwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç

e. Śe ìdánwò tí olùkö pàśç ní kíláásì

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

a. Àtç köńsónáýtì àti fáwëlì tí a yà sínú kadiboodu

b. Àwòrán êyà ara ìfõ

d. Káàdì pélébé pélébé



11.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ




12.

ÌDÁNWÒ




Yüklə 1,25 Mb.

Dostları ilə paylaş:
1   2   3   4   5   6   7   8   9   10   ...   16




Verilənlər bazası müəlliflik hüququ ilə müdafiə olunur ©muhaz.org 2024
rəhbərliyinə müraciət

gir | qeydiyyatdan keç
    Ana səhifə


yükləyin