ÕSÊ
|
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
|
ÀMÚŚE IŚË
|
1.
|
ÒWE ÀTI ÀKÀNLÒ ÈDÈ KÉÈKÈÈKÉ
ÀKÓÓNÚ
1. Ìtumõ òwe
2. Àbùdá òwe
3. ìwúlò òwe: fún àlàyé, ìkìlõ, ìmõràn, ìbáwí abbl
4. Àkànlò èdè – ìtumõ
5. Oríśi àkànlò èdè pêlú àpççrç
|
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé owe
2. Töka sí àbùdá òwe
3. Śàlàyé ìwúlò òwe pêlú àpççrç
4. Túmõ àkànlò èdè
5. Töka sí oríśi àkànlò èdè kéèkèèké pêlú àpççrç
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Pa òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó
3. pa òwe ti ara rç
4. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç
5. Śàlàyé ìyàtõ láàrin òwe àti àkànlò èdè
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. kádíböõdù tí a kô òwe àti àkànlò èdè sí.
2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òwe àti àkànlò èdè sí
|
2.
|
ÈDÈ: Òýkà Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àtúnyêwò òýkà láti oókan dé êëdëgbêta (1-500)
2. ka òýkà láti oókan dé êëdëgbêta
3. Da fígõ àwôn òýkà náà mõ.
|
OLÙKÖ
1. kô òýkà sí ara pátákó
2. śe àlàyé ìlànà òýkà
3. śe ìdánwò fún akëkõö lórí òýkà náà.
AKËKÕÖ
1. Da àwôn òýkà tí olùkö kô sí ara pátákó kô sínú ìwé rç
2. Tëtí sí àlàyé olùkö
3. Śe ìdánwò tí olùkö pèsè ní kíláásì
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. kádíböõdù
2. káàdì pélébé pélébé
|
3.
|
ÀŚÀ: Ìtàn Ìśêdálê Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìtêsíwájú ìtàn ìśêdálê Yorùbá
2. Àwôn ômô Õkànbí
3. Àwôn ôba ilê Yorùbá àti orúkô oyè wôn
4. Êyà Yorùbá àti êka èdè wôn
|
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé ìtàn ìśêdálê Yorùbá àti bí wôn śe tan káàkiri
2. Töka sí àwôn ôba Yorùbá àti orúkô oyè wôn
3. Dárúkô àwôn ìlú Yorùbá àti êka èdè tí wön ń sô
AKËKÕÖ
1. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé
2. Dárúkô àwôn ôba Yorùbá yàtõ sí ti olùkö
3. Sô díê lára àwôn ìlú Yorùbá àti êka èdè wôn
4. Tëtí sí àlàyé olùkö.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Máàpù ilê Áfíríkà àti ilê Marubaawa
2. Máàpù Nàìjíríà àti ilê Yorùbá
|
4.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé àyôkà
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àtúnyêwò àwôn àśàyàn ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere, ewì àti eré-onítàn
2. ìtàn inú ìwé ní sókí
3. Êdá ìtàn
4. Ìfìwàwêdá
5. ibùdó ìtàn
6. Àhunpõ ìtàn
7. kókó õrõ tó jçyô
|
OLÙKÖ
1. Darí akëkõö láti sô ní sókí ìtàn náà
2. Śe àlàyé ní kíkún lórí êdá ìtàn, ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn, kókó õrõ
3. Darí ìjíròrò àti eré ní kíláásì
AKËKÕÖ
1. Ka ìtàn àròsô
2. Tëtí sí àlàyé olùkö kí ó sì śe àkôsílê rê.
3. Béèrè ìbéèrè nípa ohun tí kò bá yé wôn
4. Sô ní sókí ohun tí ìwé dálé lórí
5. kópa nínú ìśeré tí olùkö darí
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. ìwé tí a yàn
2. ohun èlò ìśeré
3. orí ìtàgé
4. Àwòrán àfihàn ìśêlê àti êdá ìtàn eré.
|
5.
|
ÈDÈ: Ìsõrí õrõ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìtêsíwájú lórí ìsõrí õrõ
2. Dárúkô àwôn ìsõrí õrõ Yorùbá: õrõ-orúkô, õrõ-àpönlé, õrõ-aröpò orúkô, õrõ-ìśe, õrõ-àpèjúwe, õrõ-atökùn, õrõ-àsopõ
3. Àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë wôn nínú gbólóhùn
|
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé lórí ipò àti iśë õkõõkan nínú gbolohun
2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö
3. Darí akëkõö láti śe àpççrç tirê.
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé
3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. kádíböõdù
2. káàdì pélébé pélébé
|
6.
|
FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Dárúkô àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì
2. Oríśi fáwëlì tí ó wà
3. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì àti fáwëlì
4. Àtç köńsónáýtì àti fáwëlì
|
OLÙKÖ
1. ka álífábëêtì Yorùbá
2. Töka sí köńsónáýtì àti fáwëlì
3. Dárúkô oríśi fáwëlì
4. Śe àpèjúwe köńsónáýtì àti fáwëlì
5. Ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì pêlú àlàyé.
AKËKÕÖ
1. ka álífábëêtì têlé oluko
2. Ya köńsónáýtì àti fáwëlì sötõ
3. Śe àpèjúwe ìró kõõkan
4. Ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì
5. Tëtí sí àlàyé olùkö
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. kádíböõdù tí a ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì sí
2. káàdì pélébé pélébé
|
7.
|
ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô
ÀKÓÓNÚ IŚË
Ìtêsíwájú lórí:
1. Àśà Ìsômôlórúkô
2. Àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô
3.oríśi orúkô: orúkô àbísô, àmútõrunwá, àbíkú, oríkì, ìdílé ìnagijç abbl
|
OLÙKÖ
1. Rán àwôn akëkõö létí nípa àśà ìsômôlórúkô
2. Dárúkô àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô
3. Töka sí oríśi orúkô Yorùbá
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Dárúkô àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô
3. Töka sí oríśi orúkô pêlú àpççrç nípa ìdarí olùkö
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô
2. Àwòrán àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô
3. káàdì pélébé pélébé tí a kô oríśi orúkô sí
|
8.
|
ÈDÈ: Akókò, ìgbà àti ojú ôjö
ÀKÓÓNÚ IŚË
Ìtêsíwájú nípa:
1. Sísô àwôn àkókò tó wà nínú ôjö
2. Sísô iye agogo tó lù
3. Ìlò a.m àti p.m ní èdè Yorùbá. Bí àpççrç, Aago méje àárõ, aago kan õsán, aago méje alë abbl
|
OLÙKÖ
1. Rán akëkõö létí àkókò tó wà nínú ôjö
2. Śàlàyé agogo tó lù nípa lílo ôwö kúkurú àti gígùn
3. Töka sí õpõlôpõ àpççrç láti fi agogo tó lù hàn
AKËKÕÖ
1. Dárúkô àkókò tó wà nínú ôjö
2. Sô iye agogo tó lù nípa ìdarí olùkö
3. Śe àmúlò a.m àti p.m ní èdè Yorùbá.
4. Ya àwòrán agogo tí olùkö kô sílê sínú ìwé rç.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Aago ara ògiri
2. Àwòrán agogo lóríśiríśi
|
9.
|
ÈDÈ: Õrõ Àyálò
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì õrõ àyálò
2. Õnà tí õrõ àyálò gbà wônú èdè Yorùbá. Àpççrç; êsìn, ôrõ-ajé, òśèlú, õlàjú abbl.
3. Àwôn èdè tí Yorùbá ti yá õrõ lò bí i èdè Gêësì, Haúsá, Hébérù, Lárúbáwá
4. Oríśi õrõ àyálò pêlú àpççrç.
|
OLÙKÖ
1. Śàlàyé õrõ àyálò.
2. Śàlàyé õnà tí õrõ àyálò gbà wônú èdè Yorùbá.
3. Dárúkô àwôn èdè tí Yorùbá ti yá õrõ lò.
4. Töka sí oríśi õrõ àyálò pêlú àpççrç.
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Sô àpççrç õrõ àyálò
3. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Kádíböõdù
2. Káàdì pélébé pélébé.
|
10.
|
ÀŚÀ: Ìkíni
ÀKÓÓNÚ IŚË
Ìtêsíwájú nípa
1. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò
2. Ìkíni fún onírúurú ayçyç
3. Ìkíni fún onírúurú iśë
4. Ìkíni fún çni tí õfõ sê abbl
5. Ìśesí ní àsìkò ìkíni
|
OLÙKÖ
1. Śàlàyé oríśiríśi ìkíni
2. Jë kí àwôn akëkõö kí ara wôn nínú kíláásì
3. Tö akëkõö sönà nípa ìśesí àti ìhùwàsí ní àsìkò ìkíni
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Kí olùkö àti akëkõö bí ó ti yç
3. Hùwà bí ó śe yç ní àsìkò tí wôn bá ń kí ara wôn
4. Kô iśë tí olùkö kô sójú pátákó sílê
|
11.
|
ÈDÈ: Êrô Ayára-bí-àśá (Computer)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àlàyé lórí èrò kõýpútà
2. Oríśi kõýpútà
3. Êyà ara kõýpútà
4. Ìwúlò kõýpútà
|
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé êrô ayára-bí-àśá
2. Dárúkô oríśi kõýpútà
3. Töka sí êyà ara kõýpútà àti iśë wôn
4. Śe àlàyé ìwúlò êrô kõýpútà
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Sô ìwúlò êrô kõýpútà nípa ìdarí olùkö
3. kô iśë tí olùkö kô sójú pátákó sle sínú ìwé rç.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Êrô kõýpútà
2. Àwòrán kõýpútà àti àwôn êyà ara rê.
|
12.
|
ÀTÚNYÊWÒ IŚË
|
|
13.
|
ÌDÁNWÒ
|
|
ÕSÊ
|
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
|
ÀMÚŚE IŚË
|
1.
|
ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ
ÀKÓÓNÚ IŚË
Iśë àwôn ìsõrí õrõ nínú gbólóhùn:
1. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn.
2. Iśë tí õrõ aröpò-orúkô ń śe nínú gbólóhùn
3. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn
4. Iśë tí õrõ-àpönlé ń śe nínú gbólóhùn
|
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë ìkõõkan nínú gbólóhùn
2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö
3. Darí akëkõö láti śe àpççrç lórí tirê
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí iśë ìsõrí õrõ kõõkan
2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé
3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Kádíböõdù tí ó ń śàlàyé/ śe àpççrç iśë ìsõrí õrõ kõõkan
|
2.
|
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÊSÌN ÒDE-ÒNÍ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Kírísítíënì
2. Mùsùlùmí
3. Çkanka
4. Buda
5. Gúrúmàrajì
Ipa tí êsìn ń kó láwùjô
|
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé ipa tí êsìn ń kó láwùjô
2. Ìdí tí ìbõwõ fún êsìn çnìkejì śe śe pàtàkì láti dènà rògbòdìyàn àti ìjà êsìn láwùjô.
AKËKÕÖ
Sô ohun tí wôn gbö/ rí nípa êsìn òde òní.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Àwòrán àwôn çlësìn wõnyí níbi tí wôn ti ń jösìn sí.
|
3.
|
ÒÝKÀ: Òýkà Yorùbá láti 301 – 400
ÀKÓÓNÚ IŚË
Òýkà èdè Yorùbá láti 301 – 400.
Sô àwôn õnà tí a ń gbà śe òýkà ní ilê Yorùbá. B.a. lé - +, dín = -
|
OLÙKÖ
1.Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti oókanlélöõdúnrún dé irínwó (301-400)
2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún.
AKËKÕÖ
1. ka òýkà láti oókanlélöõdúnrún dé irínwó (301-400)
2. śàlàyé àwôn ìgbésê òýkà.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Kádíböõdù tí a kô òýkà láti oókanlélöõdúrún dé irínwó (301-400)
|
4.
|
ÈDÈ: Àkôtö Síwájú sí i
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. ìyapa ìsùpõ köńsónáýtì
2. Àtúnśe/ àtúnkô àwôn õrõ méjì tàbí jù bëê lô tí a ń kô papõ gëgë bí çyô kan tàbí méjì, b.a. nitorinaa – nítorí náà, biotilçjçpe – bí ó tilê jë pé abbl.
|
OLÙKÖ
1. Fi õpõlôpõ àpççrç gbé õrõ rê lësê kí o sì tún àlàyé śe lórí àkôtö òde òní
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö.
2. Śe àkôsílê àwôn àpççrç tí olùkö śe.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Kádíböõdù tí a kô àwôn àpççrç àkôtö òde òní àti sípëlì àtijö sí.
|
5.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà (Eré-Onítàn)
ÀKÓÓNÚ IŚË
Àśàyàn ìwé lítírèśõ àpilêkô
1. Ìtàn inú ìwé tí a bá kà ní sókí
2. Êdá ìtàn
3. Ìfìwàwêdá
4. Ibùdó ìtàn
5. Àhunpõ ìtàn
6. Kókó õrõ tó jçyô/ êkö tí ìtàn kö wa: Ìbáyému õrõ tó ń lô láwùjô bí àpççrç: éèdì, ìkôlura êsìn
7. Àwôn àśà Yorùbá tó súyô
8. Ìlò èdè: (a) ônà èdè: àfiwé, òwe, àkànlò èdè (b) Àwítúnwí, ìfìrómõrísí, ìfohùngbohùn abbl.
|
OLÙKÖ
1. Śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dá lé lórí
2. Darí akëkõö láti tún ìtàn/ eré onítàn sô ní sókí
3. Śe àlàyé lórí àwôn kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému wôn.
4. Śe àlàyé ní kíkún lórí êdá ìtàn, ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn, àhunpõ ìtàn, kókó õrõ
5. Darí ìjíròrò àti ìśeré ní kíláásì
AKËKÕÖ
1. ka eré onítàn
2. Tëtí sí àlàyé olùkö, kí ó sì śe àkôsílê rê
3. Béèrè ìbéèrè nípa ohun tí kò bá yé e.
4. Śe ìsônísókí iran eré náà
5. kópa nínú ìjíròrò àti ìśeré tí olùkö darí
OHUN ÈLÒ ÌKÖNI
1. Ìwé ìtàn tí a yàn
2. Ohun èlò ìśeré
3. Orí ìtàgé
4. Aśô eré
5. Àwòrán àfihàn ìśêlê àti êdá ìtàn eré
|
6.
|
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÀRÒKÔ AJÇMÖ-ÌSÍPAYÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àròkô ajçmö-ìsípayá
2. Àròkô aláríyànjiyàn
3. Àpççrç àkôlé lábë oríśi àròkô kõõkan.
4. Àkôlé
5. ìlapa èrò
6. Àtúntò ìlapa èrò
7. ìfáàrà
8. ìpín afõ
9. kô õrõ inú àròkô
10. ìgúnlê/ Àsôkágbá
|
OLÙKÖ
1. pèsè àkôlé/ orí õrõ kõõkan
2. Tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí àpççrç orí õrõ lábë oríśi àròkô kõõkan
3. Darí akëkõö láti śe ìlapa èrò
4. Tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo ìlapa tí ó śe
AKËKÕÖ
1. Jíròrò lórí àkôlé tí a yàn nípa títêlé ìdarí olùkö.
2. kópa nínú śíśe ìlapa èrò
3. Lo ìlapa èrò náà láti kô àròkô
|
7.
|
ÈDÈ: Àpólà- Orúkô àti Iśë rê
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìhun Àpólà-orúkô
2. Ìsõrí õrõ tí ó máa ń wáyé nínú àpólà-orúkô
3. Iśë àpólà-orúkô
|
OLÙKÖ
1. Kô oríśiríśi gbólóhùn
2. Töka sí àwôn ìhun àpólà-orúkô inú wôn
3. Töka sí ìsõrí õrõ tí ó máa ń wáyé nínú àpólà-orúkô
4. Sô pàtàkì àpólà-orúkô
AKËKÕÖ
1. Śe àdàkô àwôn gbólóhùn tí olùkö kô.
2. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ìsõrí õrõ tí ó ń jçyô nínú àpólà-orúkô àti pàtàkì rê.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn tí ó ní àpólà-orúkô àti iśë rê sí.
|
8.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Lítírèśõ Àpilêkô (Ewì)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ewì kíkà
2. Kókó õrõ ajçmö õrõ-tó-ń-lô láwùjô/ lágbàáyé.
- ìśêtöfábo, ipò obìnrin, ètò ôrõ-ajé, ìkôlura êsìn/ àśà, ìkóra-çni-ní-ìjánu nínú ìgbésí ayé õdö abbl.
3. Ônà-èdè àti ìsôwölo-èdè.
|
OLÙKÖ
1. ka ewì sí akëkõö létí
2. Śe àlàyé lórí ewì tí a kà
3. Fa kókó õrõ jáde
4. Śàlàyé ônà-èdè àti ìsôwölo-èdè tó jçyô.
AKËKÕÖ
1. Ka ewì náà sínú
2. ka ewì náà síta
3. Fi pëńsù fàlà sí ibi tí wôn kíyèsí kókó õrõ àti êkö tí wôn ríkö
4. Töka sí ônà èdè
5. Tëtí sí àlàyé olùkö
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Ìwé tí a yàn
2. Àwòrán ohun tí ewì dálé
3. Ìwé ìròyìn tí ó sô nípa àwôn kókó õrõ
|
9.
|
ÈDÈ: Àpólà-iśë àti iśë rê
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríśiríśi õrõ-ìśe bí i õrõ-ìśe:
a. çlëlà àti aláìlëlà abbl
b. agbàbõ àti aláìgbàbõ abbl
2. ìhun àpólà-ìśe
3. Pátákó àpólà-ìśe
|
OLÙKÖ
1. Kô oríśiríśi gbólóhùn pêlú àpççrç àwôn õrõ-ìśe nínú wôn àti irú õrõ-ìśe tí wön jë
2. Śàlàyé pêlú àpççrç ìhun àpólà-ìśe
3. Sô pàtàkì àpólà-ìśe
AKËKÕÖ
1. Tëtí dáradára sí àlàyé olùkö.
2. Kô àpççrç àwôn õrõ-ìśe àti irúfë èyí tí wön jë sílê
3. mënuba lára pàtàkì àpólà-ìśe
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Kádíböõdù tí ó śàlàyé léérèfé àpólà-ìśe àti iśë rê
|
10.
|
ÀŚÀ: Eré Òśùpá àti Eré Ojoojúmö
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìtumõ eré òśùpá
2. Ìtumõ eré ojoojúmö
3. Ìgbà wo ni à ń śeré òśùpá
4. Ìgbà tí eré ojoojúmö máa ń wáyé
5. pàtàkì eré òśùpá àti eré ojoojúmö
|
OLÙKÖ
1. Sô ìtumõ eré òśùpá àti eré ojoojúmö
2. śàlàyé ìwúlò àti pàtàkì eré òśùpá àti eré ojoojúmö
3. Darí akëkõö láti śe eré/ kô orin tí ó jçmö eré kõõkan
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Kô pàtàkì àti ìwúlò eré òśùpá àti eré ojoojúmö sílê
3. kópa nínú eré tí olùkö darí
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Ìwé pêlú àwòrán tí ó ń śe àfihàn àwôn tó ń śe eré òśùpá àti eré ojoojúmö.
|
11.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Lítírèśõ Àpilêkô (Ìtàn àròsô ôlörõ geere)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ibùdó àti àhunpõ ìtàn
2. Àśà tó súyô
3. Àwôn kókó õrõ tó jçmö ìśêlê bágbàmu b.a Êtö ômô ènìyàn, ìśètòfábo, Ètò ôrõ-ajé, ìkôlura êsìn/ àśà, jíjínigbé abbl.
4. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá
5. Ônà èdè àti ônà ìsôwölo-èdè
|
OLÙKÖ
1. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn náà dá lé lori
2. Śàlàyé ìbáyému àwôn àkóónú ìtàn náà (ìśêlê, kókó õrõ)
3. Jíròrò lórí ìwà êdá ìtàn pêlú akëkõö
4. Jíròrò lórí ìlò èdè àti àśà tó súyô
AKËKÕÖ
1. Ka ìtàn náà yóò sì jíròrò lórí ìśêlê inú rê (àhunpõ ìtàn)
2. Sõrõ lórí êdá ìtàn tí wön fëràn àti èyí tí wôn kò fëràn
3. Töka sí ônà èdè tí ó súyô
4. Töka sí àśà tí ó súyô
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Ìwé àśàyàn.
Ìwé ìròyìn tí ó ń fi ìśêlê tí ó fara pë ti inú ìtàn tó wáyé hàn.
|
12.
|
ÀŚÀ: Òge Śíśe
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oge síse
2. Ilà kíkô
3. Aśô wíwõ
4. Ìtöjú irun orí
5. Ìtöjú ara
6. Pàtàkì oge śíśe
7. Àléébù àti ewu nínú oge śíśe àśejù
|
OLÙKÖ
1. Tëtí sí olùkö
2. Śe ìdàkô ohun tí olùkö kô sílê ní ojú pátákó
3. kópa nínú ìmënubà pàtàkì àti àléébù oge śíśe
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Kóòmù, làálì, ôsç, ìpara, àtíke, bíléèdì omi abbl
|
13.
|
ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
|
|
14.
|
ÌDÁNWÒ
|
|