Education resource centre


YORÙBÁ L1 JSS 3 TÁÀMÙ KEJÌ



Yüklə 1,25 Mb.
səhifə9/16
tarix28.07.2018
ölçüsü1,25 Mb.
#60921
1   ...   5   6   7   8   9   10   11   12   ...   16



YORÙBÁ L1 JSS 3 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

ÈDÈ (FONÖLÖJÌ): Ìpàrójç àti Ìsúnkì

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Oríkì ìpàrójç àti ìsúnkì

2. pípa fáwëlì tó bêrê õrõ jç, b. a ; Adémölá – Démölá, ìkòkò – kòkò, iyàrá – yàrá

3. ìpàrójç láàrin õrõ méjì, b.a. Aya ôba – Ayaba, ojú ilé – ojúlé, ewé oko – ewéko abbl



OLÙKÖ

1. Śe àlàyé ohun tí ìpàrójç àti ìsúnkì jë

2. Śe àpççrç fún àwôn akëkõö

3. Darí àwôn akëkõö láti mú àpççrç ti wôn wá.



AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé lórí oríkì ìpàrójç àti isunki

2. kópa nínú ìkëkõö nípa mímú àpççrç wá

3. śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Pátákó çlëmõö tí ó ń sô oríkì ìpàrójç àti ìsúnkì pêlú àpççrç

2. Orúkô àwôn akëkõö kan fún àpççrç.


2.

ÀŚÀ: Çrú àti Ìwõfà

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àlàyé lórí çni tí çrú jë.

2. Àlàyé lórí çni tí ìwõfà jë

3. Õnà tí a fi ń ní çrú, bí àpççrç mímú lójú ogun, fífi owó rà abbl

4. Õnà tí a ń gbà lo çrú

5. Õnà tí a ń gbà lo çrú àti ìwõfà (fífi yá owó) ìwõfà.



OLÙKÖ

1. Śe àlàyé dáradára fún àwôn akëkõö lórí çni tí çrú jë àti çni tí ìwõfà jë

2. Sô õnà tí a fi ń ní çrú àti õnà tí a fi ń ní ìwõfà

3. Śe àlàyé lórí õnà tí a ń gbà lo çrú àti ìwõfà

4. Śe àfiwé ìkönilëkõö tí ìgbàlódé lô sí òkè-òkun fún òwò nàbì.

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. Śe àfiwé ômô õdõ àti ômô mõlëbí ní õdõ àwôn òbí.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Àwòrán láti inú ìwé tí ó śàfihàn çrú àti ìwõfà.



3.

ÈDÈ: Àpólà-atökùn àti iśë rê

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Ìhun àpólà-atökùn

2. Iśë àpólà-atökùn

3. Àpççrç àpólà-atökùn



OLÙKÖ

1. Śe àlàyé nípa àpólà-atokun

2. Kô àpççrç àpólà-atökùn

3. Sô nípa iśë tí àpólà-atökùn ń śe nínú gbólóhùn



AKËKÕÖ

1. Fi òye sí àlàyé tí olùkö śe

2. kópa nínú àfikún àpççrç

3. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Kádíböõdù tí ó ń śàlàyé léréèfé àpólà-atökùn pêlú àpççrç

4.

LÍTÍRÈŚÕ: Kíka Ìwé (Àśàyàn lítírèśõ àpilêkô)

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Ibùdó àti àhunpõ

2. Àśà tó súyô

3. Àwôn kókó õrõ tó jçmö ìśêlê bágbàmu b.a.

- Ètò ômô ènìyàn

- ìśêtöfábo

- Ètò ôrõ-ajé

- ìkôlura êsìn àti àśà

- jíjínigbé abbl

4. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá

5. Ônà èdè àti ônà ìsôwölo-èdè


OLÙKÖ

1. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dá lé lórí

2. Śe àlàyé ìbáyému àwôn ìśêlê inú ìtàn náà (ìśêlê, kókó õrõ)

3. Jíròrò lórí ìwà êdá ìtàn pêlú akëkõö

4. Àti lórí ìlò èdè àti àśà tó súyô

AKËKÕÖ

1. ka ìtàn náà, yóò sì jíròrò lórí ìśêlê inú rê (àhunpõ ìtàn)

2. sõrõ lórí êdá ìtàn tí wön fëràn àti èyí tí wôn kò fëràn

3. śe àfàyô ìlò ônà èdè àti ìsôwölo ônà èdè

4. śe àfàyô àśà tó súyô.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. ìwé àśàyàn

2. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tí ó fara pë ti inú ìtàn tó wáyé wà.


5.

Òýkà Èdè Yorùbá 400 – 500

ÀKÓÓNÚ IŚË

Òýkà láti irínwó dé êëdëgbêta (400-500)



OLÙKÖ

1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà- irínwó dé êëdëgbêta

2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún.

AKËKÕÖ

1. Ka òýkà láti irínwó dé êëdëgbêta (400 – 500)

2. Da òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní çyô kõõkan

3. Kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.



6.

ÀŚÀ: Çrú àti Ìwõfà

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àfiwé çrú níní, ìwõfà yíyá láyé àtijö àti ômô õdõ níní láyé òde òní.

2. Kíkó õdömôkùnrin àti õdömôbìnrin lô sí òkè-òkun lô śe çrú àti òwò nàbì.

3. Àwôn ewu tí ó rõ mö wôn.



OLÙKÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. Śe àfikún sí àfiwé tí olùkö śe nípaśê ìrírí wôn ní ilé tàbí àdúgbò wôn.

3. Mô ewu tí ó rõ mö wôn.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Ìwé tí ó ń śàfihàn çrú àti ìwõfà.




7.

ÈDÈ: Ìtêsíwájú Lórí Sílébù Èdè Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

- Àwôn õrõ tí sílébù wôn ju méjì lô b.a. olówó, ômôdé, labalábá abbl

- Ìwúlò sílébù.


OLÙKÖ

1. Kö/ śe àpççrç õrõ tí sílébù wôn ju sílébù méjì lô.

2. Śe àlàyé ìwúlò sílébù èdè Yorùbá.

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. Śe àfikún àpççrç tí olùkö śe

3. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn sílébù àpççrç àti iśë rê nínú õrõ



8.

LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà

ÀKÓÓNÚ IŚË

Àśàyàn ìwé lítírèśõ àpilêkô



OLÙKÖ

1. Śe ìtúpalê ìwé tí a yàn nípa títêlé ìlànà ìtúpalê ìwé



AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö.

2. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí böõdù

3. Kópa nínú èdè



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Ìwé tí a yàn



9.

Àròkô Aśàpèjúwe àti Oníròyìn

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àlàyé lórí àròkô aśàpèjúwa àti oníròyìn.

2. Àpççrç orí õrõ lábë ìsõrí àròkô kõõkan

3. Ìlapa èrò fún àròkô kõõkan



OLÙKÖ

1. Śe àlàyé lórí àròkô aśàpèjúwe àti Oníròyìn

2. Kô àpççrç orí õrõ tí ó wà lábë oríśi àròkô kõõkan

3. Śe àlàyé ìlapa èrò fún àròkô kõõkan.



AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìdánilëkõö

2. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô

3. Kô àpççrç àròkô oníròyìn nípa títêlé àpççrç ìlapa èrò tí olùkö sô nípa rê.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Pátákó çlëmõö tí a kô ìlànà méjèèjì sí.



10.

Òwe

Àkóónú iśë

1. Oríśiríśi òwe

2. Ìwúlò òwe

3. Àwôn tí wön ń pa òwe.



OLÙKÖ

1. Kô àpççrç oríśiríśi òwe fún àwôn akëkõö

2. Śe àlàyé àwôn tí wôn ń pa òwe àti ìlànà tí ômôdé yóò têlé bí ó bá fë pa á.

3. Sô ìwúlò òwe



AKËKÕÖ

1. Fi òye sí àlàyé tí olùkö śe.

2. Kô àpççrç oríśiríśi òwe sílê

3. Sô ìwúlò òwe



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Pátákó çlëmõö tí a kô oríśiríśi òwe sí àti ìwúlò òwe.



11.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ





12.

ÌDÁNWÒ





YORÙBÁ L1 JSS 3 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

Àkôtö Síwájú sí i

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àkôtö

1. Ìyípadà ìsùpõ köńsónáýtì

2. Àwôn õrõ tí wön ju méjì lô tí a ń kô ní õkan.



OLÙKÖ

1. Kô àwôn ìpinnu ôdún 1974 náà.

2. śe àlàyé àwôn ìpinnu náà àti àýfààní rê fún kíkô èdè Yorùbá ní àkôtö

AKËKÕÖ

1. Da ìpinnu náà kô sínú ìwé rê.

2. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àwôn ìpinnu náà lësççsç

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Kádíböõdù tí a kô àkôtö èdè Yorùbá sí.

2.

Òýkà Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí òýkà Yorùbá

1. Òýkà Yorùbá láti 301 - 350

2. 351 – 400

3. 401 – 450


OLÙKÖ

1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà ní kíkún

2. śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún

AKËKÕÖ

1. ka òýkà láti 301-350, 351 – 400, 401 - 450

2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan.

3. kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. kádíböõdù tí a kô òýkà láti 301 – 450 sí.

2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí


3.

Iśë àwôn ìsõrí õrõ nínú gbólóhùn

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí iśë àwôn ìsõrí õrõ nínú gbólóhùn

1. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn

2. Iśë tí õrõ aröpò-orúkô ń śe nínú gbólóhùn

3. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn

4. Iśë tí õrõ-êyán ń śe nínú gbólóhùn.



OLÙKÖ

1. kô oríśiríśi gbólóhùn tí ó fi iśë õrõ-orúkô, õrõ-ìśe àti õrõ aröpò-orúkô hàn sójú pátákó.

2. śe àlàyé kíkún lórí wôn.

AKËKÕÖ

1. śe ìdàkô àwôn gbólóhùn tí olùkö kô

2. Tëtí sí àlàyé olùkö

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn tí a ti lo õrõ-orúkô, õrõ-ìśe àti õrõ aröpò-orúkô sí



4.

Àśàyàn Ìwé Eré-Onítàn

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àśàyàn ìwé eré-onítàn

1. Ibùdó ìtàn

2. Àhunpõ ìtàn

3. Àśà tó súyô

4. Kókó õrõ

5. Ìfìwàwêdá

6. Ìlò Èdè



OLÙKÖ

1. Darí akëkõö láti ka eré-onítàn náà.

2. śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí eré náà dálé

3. fa àwôn kókó õrõ yô

4. jíròrò lórí êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn

5. śe àfiwé ìśêlê inú ìtàn pêlú õrõ tí ó ń lô láwùjô

6. śàlàyé lórí lílo èdè

7. Darí ìśeré ní kíláásì, ìbáà jë ìran kan tàbí méjì.



AKËKÕÖ

1. ka eré-onítàn náà

2. jíròrò lórí ìśêlê tí wön gbö rí/ kà rí tí ó fi ara pë èyí tí wön ń kà.

3. fa êkö tí wön rí kö yô

4. töka sí oríśiríśi ìlò èdè

5. jíròrò lórí àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn.

6. kópa nínú ìśeré tí olùkö darí ní kíláásì.


5.

Ìtêsíwájú Lórí Êsìn Ìbílê Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

ìtêsíwájú lórí êsìn òde oni

1. Kìrìsítíënì

2. Mùsùlùmí



OLÙKÖ

1. śe àlàyé ipa tí êsìn ń kó láwùjô

2. ipò Olódùmarè nínú êsìn òde òní

3. àjôśe tó wà láàrin àwôn çlësìn ìbílê, Kìrìsítíënì àti Mùsùlùmí.

4. śàlàyé nípa ìjà êsìn òde òní àti bí a śe lè dëkun wôn

AKËKÕÖ

1. sô ohun tí wôn mõ nípa êsìn ìbílê Yorùbá àti êsìn òde òní.

2. jíròrò àjôśe tó wà láàrin çlësìn Mùsùlùmí àti Kìrìsìtíënì

3. jíròrò lórí ìjà êsìn àti bí a śe lè dëkun rê.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Àwòrán àwôn çlësìn Kìrìsítíënì àti Mùsùlùmí níbi êsìn

2. Fídiò

3. Sínnimá



6.

Àròkô Síwájú sí i

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí kíkà àti kíkô àròkô

Oríśiríśi àròkô: àròkô ajçmö-ìsípayá, aláríyànjiyàn, aśàpèjúwe


OLÙKÖ

1. pèsè àkôlé/ orí õrõ fún àròkô ajçmö-ìsípayá, aláríyànjiyàn, aśàpèjúwe.

2. tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí õrõ náà

3. darí akëkõö láti śe ìlapa èrò

4. tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo ìlapa tí o śe

AKËKÕÖ

1. jíròrò lórí àkôlé tí a yàn nípa títêlé ìdarí olùkö

2. kópa nínú śíśe ìlapa èrò

3. lo ìlapa èrò náà láti kô àròkô



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. pátákó çlëmõö tí a kô àkôlé àwôn àròkô wõnyí sí lóríśiríśi

2. pátákó çlëmõö tí ó ń śàfihàn ìlapa èrò fún àwôn àkôlé náà


7.

ÀKÀYÉ

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àkàyé:

1. Ôlörõ geere

2. Elédè Ewì



OLÙKÖ

1. pèsè àyôkà lórí àwôn õrõ tí ó ń lô lákòókò bágbàmu

2. pèsè ìbéèrè tí ó péye lórí àwôn kókó õrõ inú àyôkà náà.

AKËKÕÖ

1. ka àyôkà tí olùkö pèsè

2. dáhùn àwôn ìbéèrè tí olùkö pèsè lórí rê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. àyôkà oríśiríśi tí ó dálé ìśêlê õrõ tó ń lô láwùjô

2. àwòrán tó bá àyôkà náà mu.


8.

Àśàyàn Ìwé Ewì

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àśàyàn ìwé ewì

1. Ìtàn inú ìwé ní sókí

2. Êdá ìtàn

3. Kókó õrõ

4. Ìfìwàwêdá

5. Ibùdó ìtàn

6. Àhunpõ ìtàn



OLÙKÖ

1. ka ewì sí etígbõö àwôn akëkõö

2. śe àlàyé lórí ewì tí a kà

3. kô àwôn kókó õrõ jáde

4. śe àlàyé ní kíkún lórí ônà èdè, êkö abbl

5. darí ìjíròrò nípa àwôn kókó inú êkö yìí ní kíláásì



AKËKÕÖ

1. tëtí sí bí olùkö śe ń ka ewì

2. ka ewì sí etígbõö ara wôn

3. tëtí sí àlàyé olùkö

4. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí ní kíláásì

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Ìwé tí a bá yàn

2. Àwòrán àwôn ohun tí ewì dálé lórí


9.

Àpólà-Orúkô àti Iśë rê

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àpólà-orúkô àti iśë rê:

i. Oríkì, Ìhun àpólà-orúkô

ii. iśë tí ó ń śe nínú gbólóhùn

iii. ìsõrí õrõ tí ó máa ń wáyé nínú àpólà-orúkô


OLÙKÖ

1. śe àlàyé kíkún lórí àpólà-orúkô àti iśë rê nínú gbólóhùn.

2. śe õpõlôpõ àpççrç lórí àpólà-orúkô àti iśë tí ó ń śe fún akëkõö.

3. darí láti śe àpççrç tirê



AKËKÕÖ

1. tëtí sí àlàyé olùkö

2. kô àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé rç

3. śe àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. kádíböõdù tí a kô àwôn àpççrç sí.



10.

Àśàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àśàyàn ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere.

1. Ìtàn inú ìwé ní sókí

2. Êdá ìtàn

3. Kókó õrõ

4. Ìfìwàwêdá

5. Ibùdó ìtàn

6. Àhunpõ ìtàn



OLÙKÖ

1. śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dálé

2. darí akëkõö láti tún ìtàn sô

3. śàlàyé lórí àwôn kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému

4. śàlàyé nípa àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn

5. darí ìjíròrò nípa ìlò èdè nínú ìtàn náà



AKËKÕÖ

1. ka ìwé náà

2. tún ìtàn náà sô ní sókí

3. jíròrò lórí kókó õrõ inú ìwé náà àti ìbáyému wôn

4. tëtí sí àlàyé olùkö nípa êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn

5 kópa nínú ìjíròrò lórí ìlò èdè



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Ìwé tí a yàn fún kíkà.

2. Àwòrán díê lára ìśêlê tó köni lëkõö nínú ìwé náà


11.

Àpólà-ìśe àti Àpólà-atökùn àti Iśë wôn

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí àpólà-ìśe àti àpólà-atökùn

1. Ìhun àpólà-ìśe

2. Ìhun àpólà-atökùn

3. Iśë àpólà-ìśe àti àpólà-atökùn


OLÙKÖ

1. śàlàyé lórí ipò àti iśë õkõõkan wôn nínú gbólóhùn

2. śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö

3. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê



AKËKÕÖ

1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ipò àti iśë õkõõkan

2. kô àwôn àpççrç tí olùkö ń śe sínú

3. śàlàyé àwôn àpççrç iśë tí õkõõkan wôn ń śe nínú gbólóhùn



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Káàdì pélébé pélébé tí a kô àpççrç iśë tí õkõõkan wôn ń śe nínú gbólóhùn sí.




12.

FONÖLÖJÌ ÈDÈ YORÙBÁ: Ìpàrójç àti Ìsúnkì

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìtêsíwájú lórí ìpàrójç àti ìsúnkì

1. ìpàrójç ìbêrê fáwëlì, b.a. Adémölá – Démölá, Ìkõkõ – kõkõ, Iyàrá – yàrá abbl

2. ìpàrójç õrõ méjì, b.a. aya ôba – ayaba, ojú ilé – ojúlé abbl



OLÙKÖ

1. śe êkúnrërë àlàyé lórí ohun tí à ń pè ní ìpàrójç àti ìsúnkì.

2. kô àwôn àpççrç õrõ tí a lè pajç tàbí súnkì nínú gbólóhùn sójú pátákó.

3. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê



AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. kô àwôn àpççrç wõnyí sí inú ìwé

3. śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Kádíböõdù tí a kô àpççrç náà sí.



13.

Àtúnyêwò Êkö





14.

Ìdánwò





BUSINESS STUDIES
BUSINESS STUDIES

JSS 3 FIRST TERM

WEEK

TOPIC/CONTENTS

ACTIVITIES

1

OFFICE PROCEDURE

  • Meaning

  • Importance

  • Procedures for preparing bills invoice and receipts




Teacher: Discuss on the meaning and importance of office procedure.

Students: Give examples of office procedure.

Specimen: bills (e.g. PHCN, NITEL bills, invoices, receipts


2

PROCEDURES FOR MAKING PAYMENT

  • Cash

  • Bank transfer

  • Cheque

  • Bank draft

  • E-payment

  • Imprest account

  • Balance and restoration of imprest

  • Store records




Teacher: Guide students to complete specimen of bills, invoices, receipts, cheques, bank drafts and e-payment.

Student: Practice preparation of vouchers, pay roll and pay slip advice.

Photographs and adding machine should be used.


3

OFFICE PROCEDURE

  1. Procedure for store procurement (use of store requisition)

  2. Importance of stock taking

  3. Delivery note, Gate pass

Teacher: demonstrate on chalkboard preparation of store records, delivery notes and store requisition

Students: Practice preparation of store records and completing a specimen delivery note and gate pass.

A chart to be used.


4

OFFICE EQUIPMENT

Office Equipment



  • Meaning of office

  • Meaning of office equipment

  • List of office equipment

  • Importance of office equipment.




Teacher: Explain the meaning of office.

Students: Identify the different types of equipment

Specimen: A chart showing the photograph of office equipment like computer, typewriter, filing cabinet, stapler, adding machine, perforator, office pin etc.


5

OFFICE EQUIPMENT

Uses of Office Equipment



  • Use of computer

  • Use of duplicating machine

  • Use of photocopying machine

  • Use of filing cabinet etc

  • Care of office equipment




Teacher: Demonstrate the uses of office equipment and guide the students on how to use and take care of them.

Students: Practice how to use office equipment and how to take care of them.

Specimen: The equipment should be brought to the class for demonstration.


6

ADVERTISING

Advertising



  • Meaning

  • Types

  • Functions




Teacher: Explain the meaning, types and functions of advertising.

Students: Explain the meaning and list types of advertising.

Specimen: A chart should be used for showing the picture


7

ADVERTISING MEDIA

Advertising Media



  • Radio

  • Television

  • Newspaper

  • Handbill

  • Magazines

  • Internet

  • Billboards etc




Teacher: outline the various advertising media and display in class pictures, newspaper and other advertising materials like radio or television.

Students: Develop advertising jingles for a common product.

Specimen: Radio or Television should be used for demonstration


8

TRANSPORTATION

  • Meaning of transportation

  • Importance of transportation in commerce

  • Types of transportation (road, rail, air, pipeline etc)

  • Advantages and disadvantages of each type of transportation.

Teacher: Explain the meaning of transportation and state the 5 types of transportation we have. Discuss the advantages and disadvantages

Students: Define transportation and list the types of transportation system we have.

Specimen: A chart should be used to show the different types of transportation.


9

COMMUNICATION

  • Post

  • Telephone

  • World wide web

  • Courier services

Teacher: Discuss on the meaning of communication and means of communication and an internet.

Students: Define communication and give examples of common means of communication.

Specimen: A telephone set, GSM Handset, computer set etc should be displayed.


10

COMMUNICATION (b)

  1. Importance of communication in business.

  2. Services provided by communication agencies

Teacher: Explain the role of communication in business and give examples of common means of communication.

Students: Discuss the importance of communication in business. Practice how to make calls.

Specimen: A chart showing the agencies.


11

SETTING SIMPLE BUSINESS GOALS.

Simple Business Goals.



  • Meaning

  • Strength

  • Weaknesses

  • Opportunities

  • Threats

Teacher: Explain the meaning of simple business goals and lead discussion on strength, weaknesses, opportunities and threat to business an entrepreneur wants to pursue.

Specimen: A chart, posters and pictures to be used.



12

SIMPLE SINGLE BUSINESS PLAN

Simple Single Business Plan






Teacher: Discuss on simple single business plan and demonstrate to students procedures for drawing up simple single business plan.

Students: Participate in class discussion and draw up simple single business plan.

Specimen: A chart or pictures should be use.


13

REVISION




14

EXAMINATION




Yüklə 1,25 Mb.

Dostları ilə paylaş:
1   ...   5   6   7   8   9   10   11   12   ...   16




Verilənlər bazası müəlliflik hüququ ilə müdafiə olunur ©muhaz.org 2024
rəhbərliyinə müraciət

gir | qeydiyyatdan keç
    Ana səhifə


yükləyin