ÕSÊ
|
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
|
ÀMÚŚE IŚË
|
1.
|
ÀŚÀ: Ìśêdálê àti Ìtànkálê Ômô Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
-
Ìśêdálê Yorùbá láti õdõ Odùduwà
-
Àwôn ìlú tí ó jë ti Yorùbá
d. Orúkô àwôn ômô Odùduwà
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé ní àgbáyé
b. Fi ìtàn àti àwòrán máàpù śe àlàyé bí Yorùbá śe śê àti bí wôn śe dé ibi tí wôn wà báyìí.b
AKËKÕÖ
a. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé.
b. Tún ìtàn náà sô
d. Kô kókó ìdánilëkõö sílê
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. Máàpù Áfíríkà àti ilê Yorùbá
b. Máàpù Nàìjíríà àti ti àgbáyé tí ó śàfihàn ìtànkálê Yorùbá.
|
2.
|
FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Álífábëêtì Yorùbá
b. Kíka álífábëêtì láti A – Y
d. Àlàyé lórí lëtà ńlá àti lëtà kékeré
e. Ìsõrí álífábëêtì èdè Yorùbá (B.a. köńsónáýtì àti fáwëlì àìránmúpè àti fáwëlì àránmúpè)
ç. Ìyàtõ láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.
|
OLÙKÖ
a. Ka álífábëêtì fún àwôn akëkõö.
b. Śe àlàyé lórí lëtà ńlá àti kékeré
d. Pín álífábëêtì èdè Yorùbá sí ìsõrí köńsónáýtì àti fáwëlì
e. Fi ìyàtõ hàn láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. Kádíböõdù tí a kô álífábëêtì Yorùbá sí.
b. Káàdì pélébé pélébé tí a kô lëtà kõõkan sí.
|
3.
|
ÀŚÀ: Ìkíni
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò (B.a. àárõ, õsán, alë, òru, ìyálêta, ààjìn abbl)
b. Ìkíni fún onírúurú ayçyç (Bí ìsômôlórúkô, ìgbéyàwó, ôlöjö ìbí, oyè jíjç, ìkíni fún aláboyún abbl).
d. Ìkíni fún onírúurú iśë. Bí àpççrç: àgbê, ôdç, akõpç, onídìrí, aláró, awakõ, alágbêdç, babaláwo abbl.
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò
b. Śe àlàyé ìkíni fún onírúurú ayçyç
d. Śe àlàyé ìkíni fún onírúurú iśë
AKËKÕÖ
a. Dárúkô àkókò àti ìgbà tó wà nínú ôjö.
b. Kí ènìyàn bí ó ti yç ní àkókò kõõkan.
d. Kí ènìyàn bí ó ti yç fún onírúurú ayçyç.
e. Kí ènìyàn fún onírúurú iśë
ç. Hùwà bí ó śe yç ní àsìkò ìkíni (B.a. ìkúnlê, ìdõbálê)
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. Pátákó tí a kô onírúurú ìkíni sí.
b. Àwòrán àwôn ômô tí wôn ń kí obi wôn.
|
4.
|
ÈDÈ: Àkàyé
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Kíka àwôn ìtàn kéèkèèké ôlörõ geere àti ewì.
b. Títúmõ àwôn õrõ tí ó ta kókó inú àyôkà.
d. Ìbéèrè àti ìdáhùn lórí àyôkà.
|
OLÙKÖ
a. Jë kí akëkõö ka àyôkà náà lëêmejì ó kéré tán.
b. Tö akëkõö sönà láti lè fa kókó õrõ inú àyôkà yô.
d. Béèrè ìbéèrè lórí àyôkà náà
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí olùkö
b. Ka àyôkà náà ni àkàsínú – àkàsíta
d. Dáhùn ìbéèrè àyôkà
e. Jíròrò lórí ìtumõ õrõ pàtàkì pàtàkì àti àkànlò-èdè inú àyôkà náà, kí o sì kô ö sínú ìwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. Pátákó ìkõwé
b. ìwé atúmõ èdè
|
5.
|
ÀŚÀ: Àśà Ìgbéyàwó Nílê Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìtumõ àti oríśi ìgbéyàwó
b. Àwôn ìgbésê ìgbéyàwó bí i ìfojúsóde, alárinà, ìtôrô, ìjöhçn tàbí ìśíhùn, ìdána abbl
d. Àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò wôn.
|
OLÙKÖ
a. śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìtumõ ìgbéyàwó
b. Jë kí àwôn akëkõö töka sí ìgbésê ìgbéyàwó
d. Kí olùkö jë kí àwôn akëkõö dárúkô àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò rê
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí olùkö.
b. Jíròrò nípa ìrírí rê
d. Da õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó kô sínú ìwé wôn.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
- Àwòrán ìgbéyàwó
- Fídíò
- Téèpù
- Tçlifísàn
|
6.
|
ÈDÈ: Àkôtö
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àtúnyêwò álífábëêtì èdè Yorùbá
b. ìtumõ àkôtö
d. sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní
e. ìyàtõ láàrin sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní.
i. Fáwëlì: aiye – ayé
yio – yóò
enia – ènìyàn, abbl
ii. Köńsónáýtì: Oshogbo - Òśogbo, abbl
iii. Àmì ohùn: õgun - òógùn
alãnu – aláàánú
iv. Yíyán õrõ nídìí: ẹ - ç , ṣ - ś, ọ - ô
v. Pípín õrõ: wipe – wí pé
nigbati – nígbà tí
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé ohun tí àkôtö jë
b. kô àkôtö àtijö àti òde òní sára pátákó
d. Śe àlàyé kíkún lórí ìyàtõ láàrin méjèèjì
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí àlàyé olùkö
b. kô àpççrç tí olùkö kô sí ojú pátákó
d. Béèrè ohun tí kò bá yé ô löwö olùkö.
|
7.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìtumõ oríkì lítírèśõ
b. Êka lítírèśõ Yorùbá
i. Lítírèśõ Àpilêkô
ii. Lítírèśõ Alohùn
d. Ìsõrí Lítírèśõ àpilêkô
i. Àpilêkô ôlörõ geere
ii. àpilêkô ewì
iii. àpilêkô eré-onítàn
e. Ìsõrí lítírèśõ alohùn
i. ôlörõ geere
ii. ewì alohùn
iii. eré-oníśe
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé ohun tí lítírèśõ jë
b. Sô çka lítírèśõ
d. pín êka kõõkan sí ìsõrí pêlú àpççrç tí ó yç
e. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin àpilêkô àti alohùn.
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí àlàyé olùkö
b. kô àwôn êka àti ìsõrí tí olùkö sô sílê pêlú àpççrç
d. kô àpççrç mìíràn sí láti ilé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
- Téèpù
- Tçlifísàn
- Rédíò
- kásëëtì àti téèpù tí a gba ohùn sí
- Fíìmù ìśeré lítírèśõ alohùn
- ìwé tí a da lítírèśõ alohùn kô sí
|
8.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Òýkà Yorùbá
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Òýkà Õödúnrún dé irínwó (300 – 400)
|
OLÙKÖ
a. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti Õödúnrún dé irínwó
b. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún
AKËKÕÖ
a. ka òýkà láti Õödúnrún dé irínwó
b. dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan
d. kô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
- Kádíböõdù tí a kô òýkà láti Õödúnrún dé irínwó
- Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí
|
9.
|
ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. õrõ-orúkô
b. õrõ aröpò- orúkô/ aröpò afarajorúkô
d. õrõ-ìśe
e. õrõ-àpèjúwe
ç. õrõ-àpönlé
f. õrõ-atökùn
g. õrõ-àsopõ
|
OLÙKÖ
a. śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë õkõõkan nínú gbólóhùn.
b. śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö
d. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí kõõkan
b. kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé
d. śe àwôn àpççrç tirê lábë ìdarí olùkö.
OHUN ÈLÒ ÌKÖNI
a. Kádíböõdù
b. Káàdì pélébé pélébé.
|
10.
|
ÀŚÀ: Òwò Śíśe àti Ìpolówó Ôjà
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. ìdí tí a fi ń polówó ôjà
b. bí a śe ń polówó kõõkan. Bí àpççrç; Ç fçran jêkô
d. ôgbön ìpolówó ôjà láyé àtijö àti lóde òní. Bí àpççrç: ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.
|
OLÙKÖ
a. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö.
b. fún àwôn akëkõö láýfààní láti śe ìpolówó ôjà nínú kíláásì.
d. kí akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ.
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê
b. kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì
d. śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. àtç
b. fídíò
d. êrô agbõrõsílê
e. Téèpù
ç. ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn
|
11.
|
ÈDÈ: Ìśêdá Õrõ-Orúkô
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. kí ni õrõ-orúkô?
b. oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç.
d. Àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé ohun tí õrõ-orúkô jë
b. śe àlàyé oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç: çja, ejò, ìyá, ôwö, êrín, adé, abö, jíjç, alaalë abbl
d. śe àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí àlàyé olùkö
b. śe àpççrç õrõ-orúkô tí a kò śêdá mìíràn
d. śe àpççrç àwôn oríśiríśi õrõ-orúkô tí a śêdá mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö ti śe.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. kádíböõdù tí a kô oríśiríśi àpççrç sí.
|
12.
|
ÈDÈ: Àròkô kíkô
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àlàyé lórí àròkô kíkô
b. Oríśiríśi àròkô
d. Ìgbésê
|
OLÙKÖ
a. Tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí aroko
b. Töka sí onírúurú àròkô pêlú àpççrç
d. śe àlàyé ìgbésê fún kíkô àròkô
AKËKÕÖ
a. Jíròró lórí àròkô
b. Tëtí sí àlàyé olùkö
d. sô àpççrç àròkô mìíràn yàtõ sí ti olùkö
e. kópa nínú śíśe àlàyé ìgbésê àròkô
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
- pátákó tí a kô oríśi àròkô sí
- pátákó tí a kô ìgbésê àròkô sí.
|
13.
|
ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
|
|
14.
|
ÌDÁNWÒ
|
|